23 O si ṣe, nigbati ẹmi buburu lati ọdọ Ọlọrun wá ba de si Saulu, Dafidi a si fi ọwọ́ rẹ̀ kọrin lara duru: a si san fun Saulu, ara rẹ̀ a si da; ẹmi buburu na, a si fi i silẹ.
Ka pipe ipin 1. Sam 16
Wo 1. Sam 16:23 ni o tọ