1. Sam 16:3 YCE

3 Ki o si pe Jesse si ibi ẹbọ na, emi o si fi ohun ti iwọ o ṣe hàn ọ: iwọ o si ta ororo si ori ẹniti emi o da orukọ fun ọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 16

Wo 1. Sam 16:3 ni o tọ