1. Sam 17:33 YCE

33 Saulu si wi fun Dafidi pe, Iwọ kò le tọ Filistini yi lọ lati ba a jà: nitoripe ọdọmọde ni iwọ, on si jẹ jagunjagun lati igba ewe rẹ̀ wá.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:33 ni o tọ