36 Iranṣẹ rẹ pa ati kiniun ati amọtẹkun na: alaikọla Filistini yi yio si dabi ọkan ninu wọn, nitoripe on ti pe ogun Ọlọrun alãye ni ijà.
Ka pipe ipin 1. Sam 17
Wo 1. Sam 17:36 ni o tọ