1. Sam 18:23 YCE

23 Awọn iranṣẹ Saulu si sọ̀rọ wọnni li eti Dafidi. Dafidi si wipe, O ha ṣe nkan ti o fẹrẹ loju nyin lati jẹ ana ọba? Talaka li emi ati ẹni ti a kò kà si.

Ka pipe ipin 1. Sam 18

Wo 1. Sam 18:23 ni o tọ