1. Sam 2:15 YCE

15 Pẹlu ki nwọn ki o to sun ọra na, iranṣẹ alufa a de, a si wi fun ọkunrin ti on ṣe irubọ pe, Fi ẹran fun mi lati sun fun alufa; nitoriti kì yio gba ẹran sisè lọwọ rẹ, bikoṣe tutù.

Ka pipe ipin 1. Sam 2

Wo 1. Sam 2:15 ni o tọ