1. Sam 2:23 YCE

23 O si wi fun wọn pe, Etiri ti emi fi ngbọ́ iru nkan bẹ̃ si nyin? nitoriti emi ngbọ́ iṣe buburu nyin lati ọdọ gbogbo enia yi wá.

Ka pipe ipin 1. Sam 2

Wo 1. Sam 2:23 ni o tọ