1. Sam 20:7 YCE

7 Bi o ba wipe, O dara, alafia mbẹ fun iranṣẹ rẹ: ṣugbọn bi o ba binu pupọ, njẹ ki iwọ ki o mọ̀ daju pe buburu ni o nrò ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:7 ni o tọ