1. Sam 21:6 YCE

6 Bẹ̃ni alufa na si fi akara mimọ́ fun u; nitoriti kò si akara miran nibẹ bikoṣe akara ifihan ti a ti ko kuro niwaju Oluwa, lati fi akara gbigbona sibẹ li ọjọ ti a ko o kuro.

Ka pipe ipin 1. Sam 21

Wo 1. Sam 21:6 ni o tọ