1. Sam 22:4 YCE

4 O si mu wọn wá siwaju ọba Moabu; nwọn si ba a gbe ni gbogbo ọjọ ti Dafidi fi wà ninu ihò na.

Ka pipe ipin 1. Sam 22

Wo 1. Sam 22:4 ni o tọ