1. Sam 23:17 YCE

17 On si wi fun u pe, Máṣe bẹru: nitori ọwọ́ Saulu baba mi kì yio tẹ̀ ọ: iwọ ni yio jọba lori Israeli, emi ni yio si ṣe ibikeji rẹ; Saulu baba mi mọ̀ bẹ̃ pẹlu.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:17 ni o tọ