1. Sam 24:3 YCE

3 O si de ibi awọn agbo agutan ti o wà li ọ̀na, ihò kan si wà nibẹ, Saulu si wọ inu rẹ̀ lọ lati bo ẹsẹ rẹ̀: Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ si mbẹ lẹba iho na.

Ka pipe ipin 1. Sam 24

Wo 1. Sam 24:3 ni o tọ