1. Sam 25:12 YCE

12 Bẹ̃li awọn ọmọkunrin Dafidi si mu ọ̀na wọn pọ̀n, nwọn si pada, nwọn si wá, nwọn si rò fun u gẹgẹ bi gbogbo ọ̀rọ wọnyi.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:12 ni o tọ