1. Sam 25:15 YCE

15 Ṣugbọn awọn ọkunrin na ṣe ore fun wa gidigidi, nwọn kò ṣe wa ni iwọsi kan, ohunkohun kò nù li ọwọ́ wa, ni gbogbo ọjọ ti awa ba wọn rìn nigbati awa mbẹ li oko.

Ka pipe ipin 1. Sam 25

Wo 1. Sam 25:15 ni o tọ