6 Akiṣi si fi Siklagi fun u ni ijọ na; nitorina ni Siklagi fi di ti awọn ọba Juda titi o fi di oni yi.
Ka pipe ipin 1. Sam 27
Wo 1. Sam 27:6 ni o tọ