1. Sam 28:12 YCE

12 Nigbati obinrin na si ri Samueli, o kigbe lohùn rara: obinrin na si ba Saulu sọrọ pe, Ẽṣe ti iwọ fi tan mi jẹ? nitoripe Saulu ni iwọ iṣe.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:12 ni o tọ