1. Sam 29:9 YCE

9 Akiṣi si dahun o si wi fun Dafidi pe, Emi mọ̀ pe iwọ ṣe ẹni-rere loju mi, bi angeli Ọlọrun: ṣugbọn awọn ijoye Filistini wi pe, On kì yio ba wa lọ si ogun.

Ka pipe ipin 1. Sam 29

Wo 1. Sam 29:9 ni o tọ