1. Sam 3:13 YCE

13 Nitoriti emi ti wi fun u pe, emi o san ẹsan fun ile Eli titi lai, nitori iwa buburu ti on mọ̀, nitori awọn ọmọ rẹ̀ ti sọ ara wọn di ẹni ẹgàn, on kò si da wọn lẹkun.

Ka pipe ipin 1. Sam 3

Wo 1. Sam 3:13 ni o tọ