1 AWỌN Filistini si ba Israeli jà: awọn ọkunrin Israeli si sa niwaju awọn Filistini, awọn ti o fi ara pa sì ṣubu li oke Gilboa.
Ka pipe ipin 1. Sam 31
Wo 1. Sam 31:1 ni o tọ