1. Sam 6:10 YCE

10 Awọn ọkunrin na si ṣe bẹ̃: nwọn si mu abo malu meji; ti nfi ọmu fun ọmọ, nwọn si dè wọn mọ kẹkẹ́ na, nwọn si se ọmọ wọn mọ ile.

Ka pipe ipin 1. Sam 6

Wo 1. Sam 6:10 ni o tọ