1. Sam 8:14 YCE

14 Yio mu ninu oko nyin, ati ninu ọgba ajara nyin, ati ninu igi olifi nyin wọnni, ani eyiti o dara julọ ninu wọn, yio si fi fun awọn ẹrú rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 8

Wo 1. Sam 8:14 ni o tọ