1. Sam 9:20 YCE

20 Niti awọn kẹtẹkẹtẹ rẹ ti o ti nù lati iwọn ijọ mẹta wá, má fi ọkàn si wọn; nitoriti nwọn ti ri wọn. Si tani gbogbo ifẹ, Israeli wà? Ki iṣe si ọ ati si ile baba rẹ?

Ka pipe ipin 1. Sam 9

Wo 1. Sam 9:20 ni o tọ