1. Sam 9:9 YCE

9 (Ni Israeli latijọ, nigbati ọkunrin kan ba lọ bere lọdọ Ọlọrun, bayi ni ima wi, Wá, ẹ jẹ ki a lọ sọdọ arina na, nitori ẹni ti a npe ni woli nisisiyi, on ni a npe ni arina nigba atijọ ri)

Ka pipe ipin 1. Sam 9

Wo 1. Sam 9:9 ni o tọ