Mat 10:21 YCE

21 Arakunrin yio si fi arakunrin rẹ̀ fun pipa, ati baba yio si fi ọmọ rẹ̀ fun pipa: awọn ọmọ yio si dide si awọn obi wọn nwọn o si mu ki a pa wọn.

Ka pipe ipin Mat 10

Wo Mat 10:21 ni o tọ