Mat 11:1 YCE

1 O si ṣe, nigbati Jesu pari aṣẹ rẹ̀ tan fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ mejejila, o ti ibẹ̀ rekọja lati ma kọni, ati lati ma wasu ni ilu wọn gbogbo.

Ka pipe ipin Mat 11

Wo Mat 11:1 ni o tọ