Mat 12:2 YCE

2 Ṣugbọn nigbati awọn Farisi ri i, nwọn wi fun u pe, Wò o, awọn ọmọ-ẹhin rẹ nṣe eyi ti kò yẹ lati ṣe li ọjọ isimi.

Ka pipe ipin Mat 12

Wo Mat 12:2 ni o tọ