Mat 12:28 YCE

28 Ṣugbọn bi o ba ṣe pe Ẹmí Ọlọrun li emi fi nlé awọn ẹmi èṣu jade, njẹ ijọba Ọlọrun de ba nyin.

Ka pipe ipin Mat 12

Wo Mat 12:28 ni o tọ