Mat 12:31 YCE

31 Nitorina ni mo wi fun nyin, gbogbo irú ẹ̀ṣẹ-kẹṣẹ ati ọrọ-odi li a o darijì enia; ṣugbọn ọrọ-odi si Ẹmí Mimọ́, on li a ki yio darijì enia.

Ka pipe ipin Mat 12

Wo Mat 12:31 ni o tọ