Mat 13:33 YCE

33 Owe miran li o pa fun wọn pe, Ijọba ọrun dabi iwukara, ti obinrin kan mu, ti o sin sinu oṣuwọn iyẹfun mẹta, titi gbogbo rẹ̀ fi di wiwu.

Ka pipe ipin Mat 13

Wo Mat 13:33 ni o tọ