Mat 13:43 YCE

43 Nigbana li awọn olododo yio ma ràn bi õrun ni ijọba Baba wọn. Ẹniti o ba li etí ki o gbọ́.

Ka pipe ipin Mat 13

Wo Mat 13:43 ni o tọ