Mat 14:22 YCE

22 Lojukanna Jesu si rọ̀ awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ lati bọ sinu ọkọ̀, ki nwọn ki o ṣiwaju rẹ̀ lọ si apakeji, nigbati on tú ijọ enia ká.

Ka pipe ipin Mat 14

Wo Mat 14:22 ni o tọ