Mat 16:27 YCE

27 Nitori Ọmọ-enia yio wá ninu ogo Baba rẹ̀ pẹlu awọn angẹli rẹ̀; nigbana ni yio san a fun olukuluku gẹgẹ bi iṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Mat 16

Wo Mat 16:27 ni o tọ