Mat 17:4 YCE

4 Peteru si dahùn, o si wi fun Jesu pe, Oluwa, o dara fun wa lati mã gbé ihin: bi iwọ ba fẹ, awa o pa agọ́ mẹta sihin; ọkan fun ọ, ati ọkan fun Mose, ati ọkan fun Elijah.

Ka pipe ipin Mat 17

Wo Mat 17:4 ni o tọ