Mat 19:23 YCE

23 Nigbana ni Jesu wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, Lõtọ ni mo wi fun nyin pe, o ṣoro gidigidi fun ọlọrọ̀ lati wọ ijọba ọrun.

Ka pipe ipin Mat 19

Wo Mat 19:23 ni o tọ