Mat 19:8 YCE

8 O wi fun wọn pe, Nitori lile àiya nyin ni Mose ṣe jẹ fun nyin lati mã kọ̀ aya nyin silẹ, ṣugbọn lati igba àtetekọṣe wá kò ri bẹ̃.

Ka pipe ipin Mat 19

Wo Mat 19:8 ni o tọ