Mat 2:2 YCE

2 Nwọn mbère wipe, Nibo li ẹniti a bí ti iṣe ọba awọn Ju wà? nitori awa ti ri irawọ rẹ̀ ni ìla-õrùn, awa si wá lati foribalẹ fun u.

Ka pipe ipin Mat 2

Wo Mat 2:2 ni o tọ