Mat 20:18 YCE

18 Wò o, awa ngoke lọ si Jerusalemu; a o si fi Ọmọ-enia le awọn olori alufa, ati awọn akọwe lọwọ, nwọn o si da a lẹbi ikú.

Ka pipe ipin Mat 20

Wo Mat 20:18 ni o tọ