Mat 21:2 YCE

2 O wi fun wọn pe, Ẹ lọ si iletò ti o kọju si nyin, lọgan ẹnyin o ri kẹtẹkẹtẹ kan ti a so ati ọmọ rẹ̀ pẹlu: ẹ tú wọn, ki ẹ si fà wọn fun mi wá.

Ka pipe ipin Mat 21

Wo Mat 21:2 ni o tọ