Mat 21:28 YCE

28 Ṣugbọn kili ẹnyin nrò? ọkunrin kan wà ti o li ọmọ ọkunrin meji; o tọ̀ ekini wá, o si wipe, Ọmọ, lọ iṣiṣẹ loni ninu ọgba ajara mi.

Ka pipe ipin Mat 21

Wo Mat 21:28 ni o tọ