Mat 23:39 YCE

39 Mo si wi fun nyin, Ẹnyin kì yio ri mi mọ́ lati isisiyi lọ, titi ẹnyin o fi wipe, Olubukún li ẹniti o mbọ̀ wá li orukọ Oluwa.

Ka pipe ipin Mat 23

Wo Mat 23:39 ni o tọ