Mat 23:4 YCE

4 Nitori nwọn a di ẹrù wuwo ti o si ṣoro lati rù, nwọn a si gbé e kà awọn enia li ejika; ṣugbọn awọn tikarawọn ko jẹ fi ika wọn kàn ẹrù na.

Ka pipe ipin Mat 23

Wo Mat 23:4 ni o tọ