Mat 24:43 YCE

43 Ṣugbọn ki ẹnyin ki o mọ̀ eyi pe, bãle ile iba mọ̀ wakati na ti olè yio wá, iba ma ṣọna, on kì ba ti jẹ́ ki a runlẹ ile rẹ̀.

Ka pipe ipin Mat 24

Wo Mat 24:43 ni o tọ