Mat 25:39 YCE

39 Tabi nigbawo li awa ri ti iwọ ṣe aisan, ti a bojuto ọ? tabi ti iwọ wà ninu tubu, ti awa si tọ̀ ọ wá?

Ka pipe ipin Mat 25

Wo Mat 25:39 ni o tọ