Mat 27:21 YCE

21 Bãlẹ dahùn o si wi fun wọn pe, Ninu awọn mejeji, ewo li ẹnyin fẹ ki emi dá silẹ fun nyin? Nwọn wipe, Barabba.

Ka pipe ipin Mat 27

Wo Mat 27:21 ni o tọ