Mat 27:27 YCE

27 Nigbana li awọn ọmọ-ogun Bãlẹ mu Jesu lọ sinu gbọ̀ngan idajọ, nwọn si kó gbogbo ẹgbẹ ọmọ-ogun tì i.

Ka pipe ipin Mat 27

Wo Mat 27:27 ni o tọ