Mat 28:2 YCE

2 Si wò o, ìṣẹlẹ nla ṣẹ̀: nitori angẹli Oluwa ti ọrun sọkalẹ wá, o si yi okuta na kuro, o si joko le e.

Ka pipe ipin Mat 28

Wo Mat 28:2 ni o tọ