Mat 4:16 YCE

16 Awọn enia ti o joko li òkunkun ri imọlẹ nla; ati awọn ti o joko ni ibi iku ati labẹ ojiji rẹ̀ ni imọlẹ là fun.

Ka pipe ipin Mat 4

Wo Mat 4:16 ni o tọ