Mat 9:16 YCE

16 Ko si ẹniti ifi idãsa aṣọ titun lẹ ogbologbó ẹ̀wu; nitori eyi ti a fi lẹ ẹ o mu kuro li oju ẹ̀lẹ, aṣọ na a si mã ya siwaju.

Ka pipe ipin Mat 9

Wo Mat 9:16 ni o tọ