Deutarónómì 1:44 BMY

44 Àwọn ará Ámórì tí ń gbé ní àwọn òkè náà, dojú kọ yín bí àgbájọpọ̀ oyin. Wọ́n sì lù yín bolẹ̀ látí Séírì títí dé Hómà.

Ka pipe ipin Deutarónómì 1

Wo Deutarónómì 1:44 ni o tọ