Deutarónómì 10:11 BMY

11 Olúwa sọ fún mi pé, “Lọ darí àwọn ènìyàn wọ̀nyí ní ọ̀nà wọn, kí wọn báà lè wọ ilẹ̀ náà, kí wọn sì gba ilẹ̀ tí mo ti búra fún àwọn baba wọn láti fún wọn.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:11 ni o tọ